Ifámúyìwá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ifámúyìwá
Ifa has brought this (for me).
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Olúmúyìwá
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-mú-èyí-wá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divinationmú...wá - bring
èyí - this (one)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL