Ifámilúsì

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifámilúsì

My Ifa is prosperous.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-mi-ní-ùsì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá (oracle)
mi - mine
ní - have
ùsì - prosperity, fame, reputation


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE
ILESHA



Irúurú

Fámilúsì