Ifámádéwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifámádéwá

Ifá brought royalty.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-mú-adé-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá (oracle)
mú...wa - bring
adé - crown
-


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fámádéwá