Ifálànọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifálànọ̀

Ifá cleared the way.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-la-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus, brotherhood
là - clear, part
ọ̀nà - path, road, way


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Fálànọ̀

Fálànà

Ifálànà

Lànà

Lànọ̀