Sísọ síta
Ifá gathered honours.
ifá-kó-ẹ̀yẹ
Ó pọ̀ ní: ONDO
Fákẹ́yẹ
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.