Ifájuyìgbé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifájuyìgbé

Ifá did not let honour go to waste.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-(ò)-jẹ́-uyì-gbé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - ifá divination/corpus/priesthood
- does not
jẹ́ - let
uyì - honour (iyì)
gbé - go to waste


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Fájuyì

Ifájuyì

Fájuyìgbé