Ifájùwọ́nlọ

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifájùwọ́nlọ

Ifá is bigger than all of your enemies.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-jù-wọ́n-lọ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá corpus, priesthood, divination
jù...lọ - be bigger/greater than
wọ́n - them


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO