Ifájẹ́midúpẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ifájẹ́midúpẹ́
1. Ifá lets me be grateful. 2. Ifá, let me have something to be thankful for.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-jẹ́-mi-dúpẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá (oracle), divination, priesthood, Ọ̀rúnmìlàjẹ́ - permit, to exist, to be effective
mi - me
dúpẹ́ - be thankful
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
ILESHA