Ifádiwúrà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifádiwúrà

Ifá has become (as precious as) gold.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-di-wúrà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá (oracle), divination, priesthood, Ọ̀rúnmìlà
di - become
wúrà - gold


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fádiwúrà

Diwúrà