Ifáṣhínà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifáṣhínà

Ifá opened the way. (See Fáshínà)



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-ṣí-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
ṣí - open
ọ̀nà - road, lane, way, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fáṣínà

Fáshínà

Shínà

Ṣínà