Ifáyẹ́misí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifáyẹ́misí

Ifá honours me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-yẹ́...sí-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, worship, priesthood, corpus
yẹ́...sí - honor, celebrate
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fáyẹ́misí

Yẹ́misí

Ifáyẹ́mi