Ifádáyìsí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifádáyìsí

Ifá preserved this (child). Ifá spared this.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is an àbíkú name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-dá-èyí-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

Ifá - ifá divination/corpus/priesthood
dá...sí - spare
èyí - this (child)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fádáyìsí

Dáyìsí

Dáìsí