Ibitáyọ̀midé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ibitáyọ̀midé

This is where my joy has come.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ibi-tí-ayọ̀-mi-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ibi - place
- that
ayọ̀ - joy, mirth
mi - me, mine
- arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL