Iṣẹ́olúwanimí
Sísọ síta
Ìtumọọ Iṣẹ́olúwanimí
I am the work of God.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
iṣẹ́-olúwa-ni-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
iṣẹ́ - work, the doingolúwa - lord, God
ni - is
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN
IFE
OTHERS