Ìyániwúrà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìyániwúrà
Mother is gold.
Àwọn àlàyé mìíràn
A notable Yorùbá proverb says "Ìyá ni wúrà, baba ni jígí. Ọjọ́ ìyá kú ni wúrà bàjẹ́, ọjọ́ ti baba kú ni jígí wọmi."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìyá-ni-wúrà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìyá - motherni - is
wúrà - gold
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL