Ìyámidé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìyámidé

My mother has returned, mother has come back.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìyá-mi-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìyá - mother
mi - mine
dé - arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL