Ìwàlọba

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìwàlọba

Character is king.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìwà-ni-ọba



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìwà - character
ni - is
ọba - king