Ìtùnúọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìtùnúọlá

The comfort that honour offers. The comfort that wealth offers.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ì-tù...-inú-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- something used for
tù... - to calm, to refresh
inú - inner parts, inside, belly, stomach
ọlá - wealth, honour, favour, glory


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ìtùnú