Ìtẹ́olúwakìíṣí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìtẹ́olúwakìíṣí
The throne of God never dulls.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìtẹ́-olúwa-kìí-ṣí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìtẹ́ - throneolúwa - God, Lord
kìí - does not, never
ṣí - to fade, to dull
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL