Ìsíjọlà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìsíjọlà

Notability/reputation is more important than wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìsì-ju-ọlà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìsì - notability (ùsì)
ju - more than
ọlà - wealth, luck, fortune


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE
ONDO



Irúurú

Ùsíjọlà