Ìranọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìranọlá

1. The vision of honour. 2. A lineage of honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìran-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìran - generation(s), genealogy, lineage
ọlá - honour, grace, wealth, success, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO