Ìjádáhùn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìjádáhùn
Ìja has answered (my prayers).
Àwọn àlàyé mìíràn
User comment: "It originated from Ìja, one of the Yoruba gods of hunting, who is regarded as the brother of Ògún, the god of iron. It is a common name among various local hunter communities across Yorùbá land, especially in the Owo, Ondo, and Ekiti region.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìja-dáhùn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sìdáhùn - answer, respond
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO