Ìfẹ́tọ̀míwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìfẹ́tọ̀míwá

Love found me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìfẹ́-tọ̀-mí-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìfẹ́ - love
tọ̀...wá - seek, come to
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tọ̀míwá