Ìbùkún

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìbùkún

Blessings. An addition.



Àwọn àlàyé mìíràn

Literally, the name means "An addition" "Ìbùkún" is a common abridged version of Ìbùkúnolúwa, Ìbùkúnadé, Ìbùkúnolú, etc.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ì-bù-kún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- something that
bù - scoop
kún - in addition to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL