Ìbítóyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìbítóyè

1. Birth is worth chieftaincy. 2. The birth that survives.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìbí-tó-oyè, ìbí-tí-ó-yè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìbí - (good) birth
tó - enough for
oyè - honour
-
ìbí - birth
tí ó - that
yè - survive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL