Ìbíyọ̀sí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìbíyọ̀sí
(Good) pedigree is worth rejoicing in.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Tóyọ̀sí
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìbí-yọ̀-sí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìbí - (good) birth, pedigree, familyyọ̀ - rejoice
sí - into
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL