Ìbíládùn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìbíládùn
Birth (of a child) has sweetness; Good pedigree has sweetness/enjoyment.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìbí-ní-adùn, ìbi-ní-adùn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìbí - (good) birth, pedigree, familyní - have
adùn - sweetness
ìbi - family, kin, generation
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA