Ìbídọlápọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìbídọlápọ̀
(Good) Birth has brought wealth from different avenues together.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìbí-da-ọlá-pọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìbí - (good) birthdà...pọ̀ - mix together
ọlá - wealth
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IGBOMINA