Gbilé

Sísọ síta



Ìtumọọ Gbilé

Flourish, thrive, fill the home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

gbà-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

gbà - fill, collect, receive, save
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Oyègbilé

Adégbilé

Olúgbilé

Ọlágbilé