Gbélégbùwà
Sísọ síta
Ìtumọọ Gbélégbùwà
One who enjoys celebration from his home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
gbé-ilé-gba-ùà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
gbé - live inilé - home, house, household
gba - to collect, to receive
ùà - the society, a gathering, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
The Awùjalẹ̀ Of Ìjẹ̀bù Ọba Daniel Adésànyà Gbélégbùwa II.