Gbọ́láwọlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Gbọ́láwọlé

Bring honour into the home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

gbé-ọlá-wọ-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

gbé - carry
ọlá - wealth, honor, success
wọ - enter
ilé - home, house, household


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Gbọ́lá