Fúnshọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Fúnshọ́

Give me to protect, a shortening of names like Olúfúnshọ́, Adéfúnshọ́, Ògúnfúnshọ́, etc.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fún-n-ṣọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fún - to give to
n - me (mi)
ṣọ́ - watch over, protect


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fúnṣọ́

Fúnmiṣọ́