Fúnmiládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fúnmiládé

(One who) gives me the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fún-mi-ní-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fún - give
mi - me
l - ní [particle]
adé - crown