Fowókẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Fowókẹ́

Cherish/pamper with money.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-owó-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - used
owó - money, cowries
kẹ́ - cherish, care for, pet


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adéfowókẹ́

Ògúnfowókẹ́

Ọ̀ṣúnfowókẹ́

Odùfowókẹ́

Ajéfowókẹ́

Ọmọ́fowókẹ́