Fireshọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Fireshọlá
Make wealth/success with goodness.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
fi-ire-ṣe-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
fi - useire - goodness
ṣe - make
ọlá - wealth, success, nobility
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL