Fìyìnfólúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Fìyìnfólúwa
Give praises to God.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
fi-ìyìn-fún-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
fi - useìyìn - praises
fún - for, to
olúwa - lord
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Fìyìnfólúwa Ọnàrìndé
writer and poet (1984 - 2015).