Fìfẹ́wámirí

Sísọ síta



Ìtumọọ Fìfẹ́wámirí

Find me with love.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ìfẹ́-wá...rí-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
ìfẹ́ - love
wá...rí - find, seek out
mi - me, mine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
IJEBU
OGUN



Irúurú

Wámirí