Fìfẹ́ṣadé

Sísọ síta



Ìtumọọ Fìfẹ́ṣadé

Make royalty with love.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ìfẹ́-ṣe-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
ìfẹ́ - love
ṣe - make
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ṣadé