Fejiṣẹwà

Sísọ síta



Ìtumọọ Fejiṣẹwà

Make beauty with rain.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-eji-ṣe-ẹwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
eji - rain
ṣe - make, create (something good)
ẹwà - beauty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ṣẹwà