Fèyíṣẹwà

Sísọ síta



Ìtumọọ Fèyíṣẹwà

Make beautify with this (one).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-èyí-ṣe-ẹwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
èyí - this (one)
ṣe - make, create (something good)
ẹwà - beauty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ṣẹwà