Fayọ̀sáyémi

Sísọ síta



Ìtumọọ Fayọ̀sáyémi

Add joy to my life.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ayọ̀-sí-ayé-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi...sí - put into, add to
ayọ̀ - joy, happiness
ayé - life, world
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL