Fadéhàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Fadéhàn

Showcase (our) royalty.



Àwọn àlàyé mìíràn

There are many roots that can be added to make this name longer. e.g. Ọmọ́fadéhàn, Olúfadéhàn, Iréfadéhàn, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi...hàn-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi...hàn - showcase
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọmọ́fadéhàn

Olúfadéhàn

Iréfadéhàn

Ògúnfadéhàn

Ọ̀ṣúnfadéhàn