Sísọ síta
Ifá saved me.
(i)fá-yọ-mí
Ó pọ̀ ní: AKURE
Ifáyọmí
Yọmí
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.