Fáwẹ̀mímọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Fáwẹ̀mímọ́
Ifá cleansed me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
Ifá-wẹ̀-mí-mọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
Ifá - Ifá divination, priesthood, corupswẹ̀...mọ́ - wash clean
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA