Sísọ síta
Ifá packaged me well.
(i)fá-tún-mi-ṣe
Ó pọ̀ ní: AKURE
Fátúnmiṣe
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.