Fátúnmibí

Sísọ síta



Ìtumọọ Fátúnmibí

Ifá re-birthed me.



Àwọn àlàyé mìíràn

See Fátúnmbí.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-tún-mi-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá corpus, priesthood, divination
tún - once again
mi - me
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL