Fáshínà
Sísọ síta
Ìtumọọ Fáshínà
Ifá opened the way. See: Fáṣínà.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-shí-ọ̀nà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, priesthood, corpusshí - open
ọ̀nà - road, lane, way, path
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IFE
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Dr. Dipọ̀ Fáshínà: retired Professr of Philosophy OAU Ile-Ife.