Fáshawẹ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Fáshawẹ̀
Ifá has created a source of healing. [verification needed]
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-ṣe-awẹ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, corpus, priesthoodṣe - make
awẹ̀ - sacred herbal pot
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI