Fáséhùn
Sísọ síta
Ìtumọọ Fáséhùn
Ifa did not withhold its voice.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-à-sé-ohùn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination/corpus/priesthoodà - does not
sé - withhold
ohùn - voice
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Frederick Fáséhùn
founder of the Oòduà People's Congress (OPC)