Fáróunbí
Sísọ síta
Ìtumọọ Fáróunbí
Ifá found something (good) to birth.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Ifáróunbí.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(i)fá-rí-oun-bí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination/corpus/priesthoodrí - see, find
oun - something, someone
bí - give birth to
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO